The Lord Jesus Christ is the way, the truth and the
life.
Ona Iye
Bass - Ona, Ona iye/ 2ce
Tenor - Mo ti mo ona iye yi,
All - Rara ko yi pada,
Tenor - Jesu ni Ona iye yi,
All – T’o lo s’ile ogo/ 5 times
Soprano - Baba ‘lawo, Ona ma ko
All – A lo si iparun
Bass – Onisegun Ona ma ko,
All – A lo si iparun.
Tenor - Mo ti mo ona iye yi,
All - Rara ko yi pada,
Tenor - Jesu ni Ona iye yi,
Al...(+)
The Lord Jesus Christ is the way, the truth and the
life.
Ona Iye
Bass - Ona, Ona iye/ 2ce
Tenor - Mo ti mo ona iye yi,
All - Rara ko yi pada,
Tenor - Jesu ni Ona iye yi,
All – T’o lo s’ile ogo/ 5 times
Soprano - Baba ‘lawo, Ona ma ko
All – A lo si iparun
Bass – Onisegun Ona ma ko,
All – A lo si iparun.
Tenor - Mo ti mo ona iye yi,
All - Rara ko yi pada,
Tenor - Jesu ni Ona iye yi,
All – T’o lo s’ile ogo/ 5 times
Alto – Baba mun ni duro,
All – kin le ba o j’oba,
Tenor – Kin duro lai ye’se,,
All - Kin de ‘joba Re.
Tenor - Mo ti mo ona iye yi,
All - Rara ko yi pada,
Tenor - Jesu ni Ona iye yi,
All – T’o lo s’ile ogo/ 5 times
Sop – Ki n ni ipin ninu re
All – Ijoba ti ko l’opin,
Tenor – K’ara ese ma se ko ba mi,
All – Kin le ba O j’oba.
Tenor - Mo ti mo ona iye yi,
All - Rara ko yi pada,
Tenor - Jesu ni Ona iye yi,
All – T’o lo s’ile ogo/ 5 times